Usman Jibrin (late) | |
---|---|
Governor of North Central State, Nigeria | |
In office 30 July 1975 – 1977 | |
Asíwájú | Abba Kyari |
Arọ́pò | Muktar Muhammed |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Àdàkọ:Birth year Nasarawa, Nasarawa State, Nigeria |
Aláìsí | 8 September 2011 | (ọmọ ọdún 68–69)
Usman Jibrin (tí a bí ní ọdún 1942 tí ó sì kú ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2011)[1] jẹ́ òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tí ó jẹ́ gómìnà ológun tí Ipinle Kaduna láti oṣù keje ọdún 1975 títí di ọdún 1977 lásìkò ìjọba ológun ti Murtala Mohammed.[2]