Uti Nwachukwu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Uti Nwachukwu Emeka 3 Oṣù Kẹjọ 1982 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Benson Idahosa University University of Nigeria, Nsukka |
Iṣẹ́ | Tv personality, actor |
Gbajúmọ̀ fún | Winner of Big Brother Africa 5 |
Awards | 2012 GIAMA "Best New Actor" |
Uti Nwachukwu (tí wọ́n bí ní 3 August 1982) jẹ́ òṣèrékùnrin àti olóòtú ètò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jara. Ọ́ wá láti Ndokwa, Aboh Kingdom, agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ndokwa East, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ní Nàìjíríà.[1][2]
Uti wá láti ìdílé elénìyàn mẹ́fà. Ìpínlẹ̀ Delta ni ó dàgbà sí, ní Ughelli lójú òpópónà Uloho. Ilé-ìwé Igbenedion Education Center ló lọ láti ọdún 1993 wọ 1999. Ó gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ computer science ní University of Nigeria in Nsukka àti oyè bachelor's degree láti Benson Idahosa University ní Benin City.[3]