Wande Coal | |
---|---|
Wande Coal in December 2018 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Oluwatobi Wande Ojosipe |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Wande Coal |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹ̀wá 1985 Lagos State, Nàìjíríà |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2006–present |
Labels |
|
Associated acts | |
Website | official website |
Oluwatobi Wande Ojosipe tí a bí ní ọjọ kejidinlogun oṣù kẹwàá, ọdún 1985, tí orúkọ ìnagijẹ rè ni jẹ Wande coal jẹ́ ọ̀kọrin ti orílé èdè Nàìjíríà àti akọ-o.[1][2]
Àbí Wande Coal ní ọjọ́ kejilelogun oṣù kẹwàá ní erékùṣù Èkó ní ìpìlè Èkó ní orílè-èdè Nàìjíríà. Orúkọ bàbá rẹ ń jẹ́ Olóyè Ìbùkún Olúfúntọ́ tí orúko ìyá rẹ̀ sì ń jẹ́ Omolará Olúwáyẹmísí ìkósínú. Wańde coal jẹ́ àbọkí láàárín ọmọ méjì tí àwọn òbí rẹ́ bi.
Ó bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé alákọ̀bẹrẹ̀ ni Staff Nursery and Primary School tí wá nì ìjànikin ní ìpínlè Èkó. Lẹ́yìn ní ọ tẹ̀sìwàjú láti lọ sí ilé ìwé ìjọba tí wọ́n pè ní Federal Government College ti ìjànikin ní ìpínlè Èkó fún ẹ̀kọ sẹ́kọ́ńdírì. O tún bọ́ tẹ́siwájú láti lọ sí ilé ìwé gíga yunifásítì tí ìlú Èkó ni bi tí o ti kẹ́kọ̀ọ́ gbọyè nínú iṣẹ́ Curriculum Studied.[3]
Wande coal bẹrẹ si kọrin ninu ẹgbẹ akọrin ọdọ ni ile ijọsin rẹ. O ni isinmi akọkọ rẹ ni ile-iṣẹ ere idaraya Naijiria gẹgẹbi onijo. O bẹ́rẹ́ iṣẹ pẹlu (wole si) Don Jazzy ní ilé iṣẹ rẹ̀ Mo' Hits Records ni ọdun 2006. O ṣe àkópá ninu Awọ orin ti [D'banj]s' Rundown/Funk you up gbé jade, àwọn orin naa sìni Loke", "Tonosibe" àti "Why Me".
".[5] Gẹ́gẹ́ bí ọkọrin tí wọ́n gbà wọlé sínú Mo' Hits, o tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Mo' Hits allstars ati pe o ṣe ipa pataki ninu itusilẹ CV ('Curriculum Vitae) album. Awo-orin ‘CV’’ àti ‘Ololufe’ jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn orin ìfẹ ti omo Naijiria nífẹ̀ẹ́ sí tí ẹnìkan kan kò tíì kọ rí. Lẹ́yìn náà, Coal ṣe àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ Mushin To Mo'Hits èyí tí ó jẹ́ ìtẹ́wọ́gbaà ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, UK àti USA.[6]
Coal tí ṣe awọ pẹ̀lú àwon ọ̀kọrin orílè èdè Nàìjíríà mìíràn bí Ikechukwu, Phyno, Davido, Naeto C, Dr SID, D'Prince, Wizkid àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀kọrin mìíràn. Ní ọdún 2012 ní ìgbésẹ nlá kan jẹwó laarin àwọn aláṣẹ Mo hits Don Jazzy ati D'banj, Coal, Dr'Prince ati [D'Prince]] fọwọ́ sí ilé iṣẹ orin tuntun tí Don Jazzy dásílẹ̀ tí orúko ilé iṣẹ náà sì ń jẹ́ Mavin Records pẹlú àfikún Tiwa Savage láti inú ilé iṣé idaraya (Record Label) tí ó ń jẹ́ 323 tí ó ń ṣe bí Ìyá-Àfin àkọkọ ti Mavin Records. Wande Coal fi Mavin Records sílẹ ní Oṣù kọkànlá ọjọ́ keje, ọdún 2013 nítorí jija ohun-ini orin kan èyí tí ọ jé ìkanna pẹlu awọn orin Don Jazzy. Ni Oṣu kọkanla ọdun 2013, o ṣe ifilọlẹ orin kan (single) tí à pè ní “Baby Face” gẹ́gẹ́ bí orin ìpínyà láàárín òhun àti Mavin Records. ..[7]
Ó gbé orin kan jáde ní ọdún 2020 èyí tí ó jé orin kàn ṣoṣo (single) tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Again", tí Melvitto ṣe.</ref> Ó kọ orin kan jade lọ́dún 2021 tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ "Come My Way" èyí tí o ń rin lọ́wọ́lọ́wọ́[8]
Year | Single | Album | Producer | Label |
---|---|---|---|---|
2008 | "Bumper2Bumper" | Mushin 2 Mohits | Don Jazzy | Mo' Hits Record |
"You Bad"
(Featuring D'Banj) | ||||
"Taboo" | ||||
"Who Born The Maga" (Featuring KaySwitch) | ||||
2011 | "Go Low" | Mavin Records | ||
"Been Long You Saw Me" (Featuring Don Jazzy) | Don Jazzy | |||
"Private Trips" | Jay Sleek | |||
2012 | "See Mi Ri" | Solar Plexus | ||
"Forever" | ||||
"Pretty Girls" | ||||
2013 | "The Kick"
(Featuring Don Jazzy) |
Don Jazzy | Black Diamond Entertainment/ Mavin Records | |
"Rotate" | Don Jazzy | Mavin Records | ||
"Baby Face" | ||||
2014 | "My Way" | Wanted | Maleek Berry | Black Diamond Entertainment |
"Baby Hello" | ||||
2015 | "Ashimapeyin" | Wanted | Sarz | Black Diamond Entertainment |
|
Wanted | Da Beat Freakz | Black Diamond Entertainment | |
2017 | "Iskaba"
(Featuring DJ Tunez) |
Spellz | Black Diamond Entertainment | |
"Ballerz" | Maleek Berry | Black Diamond Entertainment | ||
"Oh No No" | CheekyChizzy | Black Diamond Entertainment | ||
"Funkeh" | Killertunes | Black Diamond Entertainment | ||
"Turkey Nla" | Spellz | Black Diamond Entertainment | ||
2018 | "So Mi So" | Juls | Black Diamond Entertainment | |
2020 | "Again" | Juls | Black Diamond Entertainment | |
2021 | "Come My Way" | Juls | Black Diamond Entertainment |
Year | Title | Album | Director | Ref |
---|---|---|---|---|
2013 | "Rotate" | Sesan | ||
2013 | "The Kick" | Sesan | ||
2014 | "My Way" | Sesan | ||
2014 | "Baby Hello" | Wanted | Sesan | |
2015 | "Ashimapeyin" | Unlimited L.A | ||
2015 | "Same Shit" featuring AKA | Studio Space Pictures (SSP) | ||
2017 | "Iskaba" featuring DJ Tunez | Sesan | ||
2018 | "Turkey Nla" | Unlimited L.A |
|iṣẹ́=
ignored (help)
|iṣẹ́=
ignored (help)
|url=
value (help). Retrieved 2015-04-22. Unknown parameter |iṣẹ=
ignored (help)
|ọjọ wiwọle=
ignored (help); Unknown parameter |ede=
ignored (help)