Dr. Wendy Osefo | |
---|---|
Born | Wendy Onyinye Ozuzu 21 Oṣù Kàrún 1984 Nigeria |
Institutions | Johns Hopkins School of Education |
Doctoral advisor | Gloria Bonilla-Santiago |
Wendy Onyinye Osefo [1] (tí wọ́n bí ní May 21, 1984) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America. Ó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ sí ètò òṣèlú, àti gbajúmọ̀ orí èrọ̀-amóhùnmáwòrán. Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Johns Hopkins School of Education.[2] Ó ṣàfihàn nínú fíìmù àgbéléwò The Real Housewives of Potomac.[3]