YCee | |
---|---|
Ycee speaking with Flytime Promotions in December 2017 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Oludemilade Martin Alejo |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Zaheer |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kínní 1993 Lagos State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 2012–present |
Labels |
|
Oludemilade Martin Alejo (tí wọ́n bí ní 29 January 1993), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Ycee, jẹ́ olórin tàkásúfèé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]