Zainab Balogun-Nwachukwu | |
---|---|
Zainab Balogun in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Zainab Balogun 10 Oṣù Kẹ̀wá 1989 London, England, United Kingdom |
Ibùgbé | Lagos, Lagos State, Nigeria London, England |
Orílẹ̀-èdè | British Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Bachelor of Law (LLB) from the University of Kent in Medway |
Iṣẹ́ | Actress, television personality, model |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006-present |
Zainab Balogun (tí a bí ní ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1989) jẹ́ Òṣeré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìpínlè Nàìjíríà. Ó bẹ́ẹ́rẹ̀ sì ni ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún.[1] Ó wá nínú àwọn tí òlùdásílè The J-ist TV, ní ibi tí wọ́n ti má sọ̀rọ̀ nípa àṣà ilẹ̀ Áfríkà àti àwọn ọ̀rọ̀ tí ó jọ mọ.[2] Ó ṣíṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún Ebony TV ni ibi tí ó tí ń ṣe atọkun fún eto The spot. Ó ti ṣe atọkun ètò fún Jumia Tv náà.
Wọn bíi Zainab sì orile-ede London, ṣùgbọ́n àwọn òbí rẹ jẹ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ Ẹ̀gbá ni ìlú Abeokuta ni ìpínlè Ogun.[3] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Sacred Heart Rc Secondary School . Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Kent ní ibi tí ó ti kà ìwé imọ òfin.[4][5] Balogun sise fún Premier Models Management ni ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún gẹ́gẹ́ bí modelii. Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin, ó kópa nínú àwọn ère bíi Material Girls, Cocktail, The charlatans àti The Dark Knight rises . Zainab je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún ilé iṣẹ́ Ebonylife TV ni ibí tí ó tí ń ṣe atọkun fún wọn. Ó ti ṣe atọkun fún ẹtọ bíi El Now, àti The spot.[6][7]
Ní oṣù kárùn-ún ọdún 2018, Balógun fẹ́ ògbẹ́ni Dikko Nwachukwu[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], èyí tí ó jẹ́ Olùdásílẹ̀ Jetwest Airways. Àwọn méjì yìí ṣe ìgbéyàwó ìbílẹ̀ wọn ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kárùn-ún, ní ìpínlẹ̀ Èkó ní Ilẹ̀ Nàìjíríà.[8]
Balogun máa ń dá àwọn àsìkò rẹ̀ láàrin London, England, àti Lagos, èyí tí ó jẹ́ Èkó ní Ilẹ̀ Nàìjíríà.
Ọdún | Àmìn-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Èsì |
---|---|---|---|
2013 | Exquisite Lady of the Year Awards | TV Presenter of the Year | Gbàá |
2014 | Sisterhood Awards | TV Presenter of the Year | Gbàá |
2014 | All Youth Tush Awards | On-Air Personality of the Year | Gbàá |
2014 | Nigerian Broadcasters Merit Awards | Sexist On-Air Personality | Gbàá |
2014 | Exquisite Lady of the Year Award (ELOY)[9] | TV Presenter of the Year | Wọ́n pèé |
2018 | The Future Awards Africa (TFAA)[10] | Prize for Acting | Gbàá |
Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2012 | The Charlatans | Natalia | |
2012 | Material Girl | host | |
2012–present | EL Now | host, segment producer | |
2012–present | The Spot | host | |
2013 | Knock Knock | Hawa | Webseries |
2014 | VHS: Music Artist Wannabe Skit | herself | webseries |
2014 | Verdict | Lavena Johnson | webseries |
2014–present | Jumia TV | host, associate producer | |
2015– | Before 30 | Fast Girl, Ekua | |
TBA | The Island | Teni Bowen Cole |
Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2011 | The Dark Knight Rises | Dancer | Featured role |
2012 | Cocktail | Party Guest | Featured role |
2015 | A Soldier's Story | Angela | Supporting |
2016 | The Wedding Party | Wonu | Supporting |
Ojukokoro (Greed) | Linda | Supporting | |
2017 | The Wedding Party 2 | Wonu | Supporting |
The Royal Hibiscus Hotel | Ope | Lead | |
2018 | Sylvia | Sylvia | Lead |
Chief Daddy | Ireti | Supporting | |
God Calling | Sade | Lead | |
2021 | Fine Wine | Temisan | |
Charge and Bail | Boma | ||
2021 | Chief Daddy 2: Going for Broke |