Zeb Ejiro | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Isoko, Delta State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Àwọn olùbátan | Chico Ejiro (brother) |
Awards | MFR |
Zeb Éjiró jẹ́ gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Ìsókó ní ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Ẹbí rẹ̀ ni gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò tí wọ́n ń pè ní Chico Ejiro [2][3] Lọ́dún 2005, Zeb gba àmìn ẹ̀yẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà Order of the Federal Republic pẹ̀lú gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò Lérè Pàímọ́ fún akitiyan wọn fún ìdàgbàsókè sinimá àgbéléwò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà .[4]