Zubby Micheal | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Azubuike Michael Egwu Anambra State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication, Nnamdi Azikiwe University |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University |
Iṣẹ́ | Actor movie producer. |
Gbajúmọ̀ fún | His role in Three Windows. |
Azubuike Michael Egwu tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Zubby Michael jẹ́ òṣèré Nàìjíríà àti olùgbé eré jáde .[1][2] Ó jẹ́ mímọ̀ fún ipa tí ó kó nínú Three Windows, Royal Storm àti Professional Lady. Ìfarahàn rẹ̀ àkọ́kọ́ jẹ́ nínú eré tí a pe àkọlé rẹ̀ ní Missing Rib ṣùgbọ́n ó jẹ́ mímọ̀ nínú eré The Three Windows níbi tí ó ti kó ipa tó síwájú.[3]
Zubby jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Anambra State. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Nnamdi Azikiwe University níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ mass communication.[4]
Ó bẹ̀rẹ̀ eré ìtàgé ní Yola, Ipinle Adamawa ní ìgbà èwe rẹ̀.[5] Eré àkọ́kọ́ tí ó ti farahàn jẹ́ nínú eré tí a pe àkọlé rẹ̀ ní Missing Rib ṣùgbọ́n ó gbajúmọ̀ fún ipa tó síwájú tí ó kó nínú The Three Windows. Zubby síì ti farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré míràn.[6][7]
Ní 25 November 2019 a yan Zubby sínú ipò òṣèlú gẹ́gẹ́ bí agbani ní ìmọ̀ràn pàtàkì lórí ayélujára fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra State Gómìnà Willie Obiano.[8][9] Wọ́n fún-un ní ìwé èrí ìdánimọ̀ fún akitiyan rẹ̀ lórí ètò ìróni l'àgbára fún àwọn ọ̀dọ́ ti City Radio 89.7 FM ní ìpínlè Anambra.
Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Àbájáde |
---|---|---|---|
2019 | City People Movie Awards | Best Actor of the Year (Igbo)[10] | Wọ́n pèé |
City People Movie Awards | Best Actor of the Year (English)[11] | Wọ́n pèé | |
Nigeria Achievers Awards | Best Lead Actor of the Year (English)[12] | Wọ́n pèé | |
South South Achievers Awards (SSA)[13] | Male Actor of the Year | Wọ́n pèé | |
2018 | South East Entertainment Award | Movie icon of the year | Gbàá |
City People Movie Awards[14] | Best Actor Of The Year (English) | Wọ́n pèé | |
2015 | Nigerian Entertainment Award[15] | Actor of the Year (Indigenous Films) | Wọ́n pèé |
City People Movie Awards[16] | Best Supporting Actor of the Year (English) | Wọ́n pèé | |
2014 | City People Movie Awards[17] | Best New Actor of the Year (English) | Wọ́n pèé |
2011 | Best Of Nollywood Awards (BON)[18] | Most Promising Act (male) | Wọ́n pèé |
Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Àbájáde |
---|---|---|---|
2020 | South-East Beauty Pageant Organisation | Best Celebrity Politician of the Year | Won |
2019 | City People Movie Awards | Best Igbo Film of the Year (Eze ndi Ala)[10] | Nominated |
2018 | The Nigerian MSMEs & Achievers Awards | Nollywood Personality of the Year | Won |
Ọdún | Orúkọ ìwé-ìròyìn |
---|---|
2019 | A New Touch of Africa (spring/summer 2019 edition)[19] |
Ọdún | Ibi ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò |
---|---|
2021 | KingsPrimeTV [20] |
2019 | BBC news Igbo[21] |
A New Touch of Africa[22] |
Ọdún | Orúkọ | Ojúṣe | Àwọn akópa | |
---|---|---|---|---|
2021 | Bloody Doings | Ugonna | Starring Jerry Amilo | |
2020 | Omoghetto:The Saga | Azaman | ||
Identical Twins | ||||
Bad Omen | ||||
Burial Battle | ||||
Audio Money | ||||
Egg of love | ||||
2019 | The Return of Dangote | |||
Our Father's Property | Ebuka | |||
Dying of Thirst | Uzor | |||
Blood Feud | Reuben | |||
Children obey your parents | Azubuike | |||
Hunchback Princess | Ugo | |||
Seed of Greatness | Agumba | |||
A Thousand War | Obidi | |||
G4 The Money Men | Obinwanne | |||
Flashback | Chris | Starring Rachael Okonkwo | ||
Seed of Deception | Chima | |||
Enemy of Progress | Uzondu | |||
Shameless Sisters | Starring Lizzy Gold | |||
Yahoo King | King Ezego | |||
Boy Makes Money | Uzodimma | |||
Son of No Man | Nnanna | |||
The Return of Eze Ndi Ala | Eze | Starring Ken Erics, Rachael Okonkwo | ||
Afraid to Fall | James | |||
Pains of the Orphan | Prince Chimaobi | |||
2018 | Throne of Terror | |||
Sound of Calamity | Prince Irudike | |||
Lack of Money | Joshua | |||
Hunted Bride | Prince Ahamefula | Starring Eve Esin | ||
Omenka | Prince Obieze Nnoruka | Starring Queen Nwokoye | ||
Yahoo Shrine | Jide | |||
Bastard Money | Lazarus | |||
Made in South | Edozie | |||
Anayo China | Anayo | |||
Wasted Authority | Collins | Starring Ngozi Ezeonu | ||
Youngest Wife | Festus | |||
The one man squad | Victor | |||
Mama | Starring Liz Benson | |||
2017 | Eze Ndi Ala in America | Eze | Starring Ken Erics, Rachael Okonkwo | |
The King of Vulture (Eze K'udene) | ||||
Mr Arrogant | Arinze | |||
The Return | Igwe Ufuma | Starring Chacha Eke | ||
War for love | Dennis | Starring Rachael Okonkwo | ||
Ozoemena Ozubulu | Ozoemena | |||
Adaure, My love | Izunna | Starring Rachael Okonkwo | ||
Sword of Justice | Prince Ogugua | Starring Ken Erics, Ngozi Ezeonu | ||
2016 | Family Matters (Akara Ayasago) | Tony | Starring Ebere Okaro | |
2015 | 1st Hit | Gallardo | Starring Nonso Diobi and Mayor Ofoegbu | |
The Promise | Izu | Starring Chacha Eke | ||
Abba | Chibueze | Starring Queen Nwokoye | ||
Okada 50 | Okada 50 | Starring Ebere Okaro | ||
Compound fools | Ossai | Starring Kenneth Okonkwo, Yul Edochie Queen Nwokoye and Funke Akindele | ||
My love, my mother's wish | Ikechukwu | Starring Rachael Okonkwo | ||
Settle Me | Agozie | Starring Ken Erics, Ngozi Ezeonu | ||
The Struggle | Alfred | Starring Kelvin Books Ikeduba |