Yunifásítì ìlú Màídúgùri |
---|
Yunifásítì ìlú Màídúgùri jé yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó wà ní ìlú Maiduguri ní Ipinle Borno. A da kalè(pèlú àwon yunifásitì mefa miran) ni odun 1975 [1], olori yunifásitì náà ni òjògbón Aliyu Shugaba [2]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |